Feeds:
Posts
Comments

Posts Tagged ‘Yoruba names’

Orúko mi ni Títílayò Àjoké Layiwola. (My name is Títílayò Àjoké Layiwola.)

Osu méjì ti lo ti mo ti wa ni Naijiria. Mo ti di omo Yorùbá bayìí. Mo ti fi orúko òyìnbó mi sílè patapata. Nígbá ti mo pade ènìyàn tuntun, mo máa n fi ara mi han bi Títílayò. Nigba mìíràn, wón máa n beere nipa orúko mi gangan, orúko abenibi mi. Mo máa so wi pé, “mo ti fi oruko náà sílè. Títílayò lorúko mi.” Inu won máa n dun gan lati gbo yìí. Léhìn náà wón máa beere lówó mi pé “Se o mo ìtúmò rè? Ki ni ìtúmò Títílayò?” Mo máa dahun pé “Ey now, mo mo ìtúmò rè. Mo yan fun ara mi. Ìtúmò ni wi pé mo máa ní ayò titi titi laelae. Ayò mi kò ni duro.” Won máa rerin tábì won máa so “patewo fun ara rè.” Mo si tun féràn bi orúko inagije mi se gbo, Títí. Mo féràn rè. Idi gidi wà tí mo yan orúko Títílayò bi orúko Yorùbá mi. Mo rò pé orúko yìî ba ihuwasi mi mu daadaa. Mo máa n saba rérìn. Inú mi máa n saba dun. Kò wópò pé inu mi máa baje. Nítorí náà, ní odún méta sèyìn, lojó kinni kiláàsi Yorùbá ni Yunifasiti ti Wisconsin, ni mo yan orúko Títílayò.

Àbíké àti emi n rérìn si aworan kan ti oun yan. (Abike and I laughing at a picture she took.)

Now, after two and a half months of immersion in Yorùbá culture and language, I feel myself embodying my Yoruba name of Títílayò much more than my English name of Caraline. Caraline or Cara (everyone calls me Cara) is a beautiful name, and I really do like it, but it doesn’t feel like me any more. Títí (pronounced Tee-tee) just fits now with my personality, the way I feel and the way I look. It is foreign to me to hear someone calling me Cara. It is harsh on my ears. Cara. Títí. I don’t know what will happen when I get back to the States, but I think I will be fine with any of my friends and whoever wants to calling me Títí.

Read Full Post »

%d bloggers like this: